Thursday, 23 December 2021

AWON IBERE META GBANKOBI. (ORIN DAFIDI 34:12-14)

IFAARA

Ile aye ti awa yi kun fun  ogun
O ye ka gbe ara wa sori osunwon lati mo Awon okunfa ogun wonyii  ati ona abayo.

Oba Dafidi salaye okunfa ogun ati ona abayo fun wa ninu O.D.34:12-14..

Onkowe yi lo  ibere ti a n bere lowo ara eni ti a si dahun re fun ra wa retorika (Rhetorical Question.)

Awon ibere na ko nilo ki a damu ki ato ri iidahun si won, awon idahun  naa
wa  larowoto  wa.
Alaaye Lori Awon Ese Bibeli Ti  Aka: (ORIN Dafidi 34:12-14)
 

IBERE.

Ese 12

1) Tani n fe iye?
2) Tani n fe ojo pupo?
3) Tani fe se rere?
 

Ko si eniti yo so pe oun ko fe awon nnkan meta wonyii. Kosemoni ni won je.
 

IDAHUN.


Ese 13

1)Pa 'hon re mo kuro ninu ibi.
2)Ete re mo kuro ninu etan si so.
3)Lo kuro ninu ibi
 

Ese 14.

4) Ma se rere.
5) Ma wa alafia.
6) Ma lepa alafia.

IKAADI:

Bi a ba tele awon ilana wonyi a o ni isinmi ologo fun aye wa. Bere fun aanu ati oore-ofe lati odo Jesu Kristi Oluwa fun aseyege.

ALUFA P.A.ADELEKE.

No comments:

Post a Comment